Now PlayingListen, share and support
01 About this Song
A powerful Yoruba praise anthem that magnifies the greatness, wisdom, and unmatched glory of Olódùmarè. Through rich call-and-response chants and deep spiritual poetry, the song celebrates God’s eternal reign, victorious power over death, and His overwhelming glory in heaven and on earth. It is a heartfelt expression of worship, awe, and unending praise to the Most High King.
02 Lyrics of Ranti Timothy - IYIN OGO
Call:Iyin ogo loye ledumare
Res:Oba nla nla , nla nla nla nla
Call: Iyin ope loye atofarati
Res: Jaburata Ninu orun
Nitoripe;
iyin Oluwa, Lenu mi o , Koni sai loo, Kari aye
Ayo olorun , lookan mi o, koni sai ja tan tan
1) Call:Mojoko mose siro
Res: Oye wi funmi, Popeye ooo, Baaba, Oba mimo
Call: Mojoko mosasa ro
Res: Imo fiye mi,Pe wo loto,
Lati fiyin fun ,Oloruko nla,
Karabata, niinuu orun,
toota sanmọ,Biẹni tẹ́nì,
kọ́ni bere, kódé tún lópin,
Kọ́ni pila, Akiteti ayé,Oba ńlá
Orísun imo, èní ńlá
Àpótí Ọgbọ́n, gbogbo òmíràn
Fenfe Fenfe, to kárí ayé
Erimo erimo, toogborun kan
Aaawuwo, màmá seegbe
Gbingbin ninkin, ode orun
Dansaki rẹ, eeha, moberi fún o
2.)Call :Awamaridi elédùmarè, jaburata nínú ola nla
Call: Àditu nínú ọrùn tó gaju,
Res: kerebete nínú ògo
Nitoripe,
óorúkọ re, tí toobi tó,
Aagbára rẹ, kòde là fi we,
Enitadite pá, kò má bá borí
Tojinde, Nínú òkú,
Ọgbà gbàrà, lowo ikú, àti sá òkú
Itiju nla, fawon olote
Ẹri ńlá, igbagbo àwa
Dansaki rẹ ẹ háà, ọba to lógo
Res:Oba nla nla , nla nla nla nla
Call: Iyin ope loye atofarati
Res: Jaburata Ninu orun
Nitoripe;
iyin Oluwa, Lenu mi o , Koni sai loo, Kari aye
Ayo olorun , lookan mi o, koni sai ja tan tan
1) Call:Mojoko mose siro
Res: Oye wi funmi, Popeye ooo, Baaba, Oba mimo
Call: Mojoko mosasa ro
Res: Imo fiye mi,Pe wo loto,
Lati fiyin fun ,Oloruko nla,
Karabata, niinuu orun,
toota sanmọ,Biẹni tẹ́nì,
kọ́ni bere, kódé tún lópin,
Kọ́ni pila, Akiteti ayé,Oba ńlá
Orísun imo, èní ńlá
Àpótí Ọgbọ́n, gbogbo òmíràn
Fenfe Fenfe, to kárí ayé
Erimo erimo, toogborun kan
Aaawuwo, màmá seegbe
Gbingbin ninkin, ode orun
Dansaki rẹ, eeha, moberi fún o
2.)Call :Awamaridi elédùmarè, jaburata nínú ola nla
Call: Àditu nínú ọrùn tó gaju,
Res: kerebete nínú ògo
Nitoripe,
óorúkọ re, tí toobi tó,
Aagbára rẹ, kòde là fi we,
Enitadite pá, kò má bá borí
Tojinde, Nínú òkú,
Ọgbà gbàrà, lowo ikú, àti sá òkú
Itiju nla, fawon olote
Ẹri ńlá, igbagbo àwa
Dansaki rẹ ẹ háà, ọba to lógo
03 Listener Comments
0 Comment(s)



