Now PlayingListen, share and support
01 About this Song
A triumphant Yoruba worship song that proclaims the supremacy and uniqueness of God above all powers, kings, and idols. With bold call-and-response declarations, the song testifies to His unmatched strength, creative authority, and miraculous works—from bringing light out of darkness to providing for Israel in the wilderness and parting the Red Sea. It is a celebration of God’s name, Awamaridi, the Almighty Creator and victorious King, worthy of all honor, praise, and reverence.
02 Lyrics of Ranti Timothy - Agbara Oluwa
Call: Ninu gbogbo agbala aye oo
Res: Koseni to lagbara re
Call: Ninu gbogbo eniyan too daa
Res: Koseni ta le fi o we
Call: Ninu gbogbo orisa aye
Res: kosiyi to dabi re
Call: Ninu gbogbo awon oba alade
Res: Koseyi to lokiki re
Elese elewi
Etunlewi etunlese
Elepa eleji
Etunleji etunlepa
Awamaridi Loruko re
Olorun gbogbo aye ee
Awamaridi Loruko re
Olorun to da aye
2)
Call:Osoro sokunkun aye
Res: Imole ba Bo gbogbo aye
Call : Osoro fo mi to bo aye
Res: Iyangbe ile de wu jade
Call: Omi imi iye serupe ile
Res: Eniyan olorun de wu jade
Call: Opase Ori fe mi erupe lasan
Res: Lati joba Lori ohun toda
Chr...
3) Call: O Lana to po laginju
Res: Komi Israeli le ro na lo
Call : O ro Jo manna laginju
Res: Ko mo Israeli le jeun yo
Call: Opin okun pupa si meji
Res: Iseyanu ti ko lafi we
Call: Ogun farao bo mi lo
Res: Ajulo fogun alawomo
Call: Omo Israeli wo kenani
Res: Alese lewi, oba nla
Res: Koseni to lagbara re
Call: Ninu gbogbo eniyan too daa
Res: Koseni ta le fi o we
Call: Ninu gbogbo orisa aye
Res: kosiyi to dabi re
Call: Ninu gbogbo awon oba alade
Res: Koseyi to lokiki re
Elese elewi
Etunlewi etunlese
Elepa eleji
Etunleji etunlepa
Awamaridi Loruko re
Olorun gbogbo aye ee
Awamaridi Loruko re
Olorun to da aye
2)
Call:Osoro sokunkun aye
Res: Imole ba Bo gbogbo aye
Call : Osoro fo mi to bo aye
Res: Iyangbe ile de wu jade
Call: Omi imi iye serupe ile
Res: Eniyan olorun de wu jade
Call: Opase Ori fe mi erupe lasan
Res: Lati joba Lori ohun toda
Chr...
3) Call: O Lana to po laginju
Res: Komi Israeli le ro na lo
Call : O ro Jo manna laginju
Res: Ko mo Israeli le jeun yo
Call: Opin okun pupa si meji
Res: Iseyanu ti ko lafi we
Call: Ogun farao bo mi lo
Res: Ajulo fogun alawomo
Call: Omo Israeli wo kenani
Res: Alese lewi, oba nla
03 Listener Comments
0 Comment(s)



