Now PlayingListen, share and support
01 About this Song
“Iranlọwọ Ẹ̀dá” by OrisunIbukun is a powerful live worship performance recorded during an inspiring OpenFloor Session — a platform dedicated to showcasing authentic worship, live spiritual expressions, and soul-lifting music experiences.
02 Lyrics of OrisunIbukun - Iranlọwọ Ẹ̀dá (Open Floor Session)
Iranlowo eda aye o
Olorun rami lowo
Ma 'jo re mi kin to rii anugba
Je oluranlowo Mii
Awon to ye kan ran Mii lowo
Won tii gbagbe Mii
Baba ranti mii
Eni oba sa'anu lonrii anu gba
se'bi eni oba dasii nikan lon yege
agbara Mii o gbe
Ipa Mii oka
Olorun ran Mii lowo
Opo ota lo fo'ju Jo ore
Afoju fenii mama fokan feni
Ale ire Eni nii Koko
Ni gbagede wa tun se'bi ore.
Olorun pawon lenu mo
gbo oluwa ,Jo wo gbo ebe Mii
gbo oluwa , Jo wo gbo adura Mii
Aanu ta tun itan Mii ko
lati ipinle waa
Bi jephta tii Anu gba
Nibiti atii koo
Atunpe PE kowa j'olori
kowa je olori won
aanu TA tun itan Mii koo
je kin rii gba ah ah
Ni akoko
Olorun rami lowo
Ma 'jo re mi kin to rii anugba
Je oluranlowo Mii
Awon to ye kan ran Mii lowo
Won tii gbagbe Mii
Baba ranti mii
Eni oba sa'anu lonrii anu gba
se'bi eni oba dasii nikan lon yege
agbara Mii o gbe
Ipa Mii oka
Olorun ran Mii lowo
Opo ota lo fo'ju Jo ore
Afoju fenii mama fokan feni
Ale ire Eni nii Koko
Ni gbagede wa tun se'bi ore.
Olorun pawon lenu mo
gbo oluwa ,Jo wo gbo ebe Mii
gbo oluwa , Jo wo gbo adura Mii
Aanu ta tun itan Mii ko
lati ipinle waa
Bi jephta tii Anu gba
Nibiti atii koo
Atunpe PE kowa j'olori
kowa je olori won
aanu TA tun itan Mii koo
je kin rii gba ah ah
Ni akoko
03 Listener Comments
0 Comment(s)



