Mo worship a.k.a Eriimole

Mosorire


18
164
43
0
Category: Gospel

The song talks about how blessed I am for Jesus to come suffer and die a
terrible death for the sins He didn't commit just for me to have hope eternal after His resurrection.

His resurrection brought hope of joy, hope of peace.

Through His resurrection, the hold of the devil over me broke.

I now have freedom in Christ which made me powerful by the Holy Ghost.


Release Date:





Lyrics of Mo worship a.k.a Eriimole - Mosorire

CHORUS
Ah! Mo sorire o
Modupe, mo sorire o
Ah! Mo sorire o
Modupe, mo sorire o
Iya aimo di ni Jesu Je
Iku Oro lotun ku funmi
Ajinde re lofi se edidi ireti funmi

Agun Jesu Loko egbe o
Atun fun Loti kikan dipo omi
Anaa atun de lade egun
Ki ireti Le je temi tire
Leyin ajinde
Aje Niya asi pon loju o
Amu bi odo aguntan fun pipa o
Oyadi ni waju olurerun
Ki ireti Le je temi ti re
Leyin ajinde
Chorus

Call Jesu jinde
Response ah! Ireti ayo ti de
Call Jesu jinde
Response ireti alafia wole de
Call Jesu jinde
Response alleluia mo yege
Moti gba agbara isodomo
Call ibanuje osi funmi mo o
Response ah ireti ayo ti de
Call ijegaba esu ti dopin
Response ireti alafia wole de
Call ati somi da alagbara o
Response Moti gba agbara isodomo
Call moti gbagbara emimimo
Response ah ireti ayo ti de
Call aso ipele tempili ti faya
Response ireti alafia wole de
Call mo dominira ninu Jesu
Response alleluia moyege
Moti gba agbara isodomo
Alleluia, alleluia, alleluia, alleluia
Mo sorire



43 Comment(s)