Pastor Oludamola Famoriyo

ONISEARA


17
69
7
0
0pts
Category: Gospel
ONISEARA talks about God and His works of wonders. God will surely do miracles beyond your expectations through this song in your life. Remain blessed.

Release Date:





Lyrics of Pastor Oludamola Famoriyo - ONISEARA

ONISEARA
Oniseara onise iyanu x4
Oba to lemi mi o, oba to laye mi
Ekerin ninu Inan, olorun aperire,

A a a a Oniseara onise iyanu x4

Oba to ro ba nipo o, oba to n fo ba sipo
Alagbada Inan nio, alawo tele oru ni,
Oba to lo kanrin kese, Akoda aye,
Adagba matepa o, adagba ma dogbo

A a a a Oniseara onise iyanu x4

Interlude

A a a a, Oniseara onise iyanu ni
Oba to n ji oku dide, oba to n maro larada,
Alagbara giga o, Onise iyanu ni
Olorun awan olorun, onise iyanu

Oniseara onise iyanu x2
Adagba ma te pa o, adagba ma do gbo,
Oba to lo Karin kese, Onise iyanu ni
Oba la anan o, oba lo Oni o,
Akoda aye ni o, aseda orun nio,

A a a a Oniseara onise iyanu x2
Oba la anan o, oba ni bi gbogbo o,
Oba to n ji oku dide, oba to n maro larada,
Oba to laju afoju o, onise iyanuni,
Oniseara onise iyanu,
Wa sise iyanu o, wa sise itusile,
Oba awan oba, onise iyanu ni

A a a a Oniseara onise iyanu x2
Wa sise Ara o, wa sise iyanu o,
Ninu ebi wa o, onise iyanu ni

Oniseara onise iyanu ni x2
Oba to n laju afoju o, onise iyanu ni,
oba to n maro larada, onise iyanu ni

A a a a, Oniseara onise iyanu x4



7 Comment(s)
DeMirakulus
5 months ago

💥💥
He still does wonders. Hallelujah,!

Mrs Famoriyo
5 months ago

Thanks 🙏 be to God for the miracle He did through this song, I'm happy it finally out for people to be blessed

Dolapo Amusan
5 months ago

This song has always been a blessing.
God bless you Sir

More grace in Jesus name

Well composed I Love it

I love this???
We welcome the Miracles of God!??

Sam Adenuga
5 months ago

Finally my favorite is out. What a blessing listening to this finally.